"Ibeere 36: Bawo ni sisalamọ ati dida salamọ pada?"
"Idahun- Musulumi o sọ pe:«As Salāmu alaykum wa rahmotuLloohi wa barakaatuHu» "
Ọmọ-iya rẹ maa da a lohun pe:«Wa alaykumus salāmu wa rahmotuLloohi wa barakaatuHu» " "O wa ni Tirmidhiy ati Abū Dāud ati awọn to yatọ si awọn mejeeji."