"Idahun- «AlhamduliLlāhi»."
"Ki ọmọ-ìyá rẹ tabi ọrẹ rẹ o sọ fun un pe: «Yarhamuka Llāhu»."
"Ti o ba ti waa sọ ọ fun un: ki o yaa sọ pé: «Yahdīkumu Llāhu wa yuslihu bālakum» " "Al-Bukhāriy ni o gba a wa."