"Idahun- Idakeji ṣiṣe dáadáa ni ṣíṣe aida. "
*Ninu iyẹn ni: Gbígbé imọkanga ju silẹ nibi ijọsin fun Ọlọhun ti ọla Rẹ ga
"Ṣiṣẹ obi mejeeji "
Gige okun ebi.
Aladugboo buruku
"*Ati gbigbe ṣiṣe daadaa si awọn talaka ati alaini ju silẹ, ati eyiti o yatọ si iyẹn ninu awọn ọrọ ati iṣẹ buruku."