"Idahun- ina-apa: Oun ni nina owo ni ọna ti ko lẹtọọ,"
Idakeji ẹ: Ahun: Oun ni ki eeyan ma ṣe ẹtọ rẹ fun un.
"Eyi to tọ ni wiwa laarin mejeeji, ki musulumi si jẹ ọlọrẹ. "
Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: "{Àwọn tí ó jẹ́ pé nígbà tí wọ́n bá náwó, wọn kò ná ìná-àpà, wọn kò sì ṣahun; (ìnáwó wọn) wà láààrin ìyẹn ní ìwọ̀ntún-wọ̀nsì 67}. " "[Surah Al-Furqan : 67]"