"Idahun- Oun ni afihan ati iwadii nipa awọn ihoho awọn eniyan ati nnkan ti wọn n bo. "
"Ninu awọn aworan ẹ ti a ṣe ni eewọ ni: "
Wíwo ihoho awọn eniyan ninu awọn ile wọn. "
Ki eniyan maa tẹti gbọ ọrọ awọn ijọ kan ti wọn ko si mọ̀ si i. "
Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: "{Ẹ má ṣe tọpinpin ara yín...}." [Suuratul-Hujuraat 12].