"Ibeere 22: Ki ni n jẹ Al-Gībah (Ọrọ ẹyin)?"

"Idahun- Oun ni didarukọ ọmọ-ìyá rẹ musulumi pẹlu nkan ti o korira ti oun ko si si nibẹ."

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: "{Kí apá kan yín má ṣe sọ̀rọ̀ apá kan lẹ́yìn. Ṣé ọ̀kan nínú yín nífẹ̀ẹ́ sí láti jẹ ẹran-ara ọmọ ìyá rẹ̀ t’ó ti kú ni? Ẹ sì kórira rẹ̀. Ẹ bẹ̀rù Allāhu. Dájúdájú Allāhu ni Olùgba-ìronúpìwàdà, Àṣàkẹ́-ọ̀run 12}" [Suuratul-Hujuraat 12].