"Idahun- Oun ni ti tanmọọn yiyẹ idẹra kuro lọdọ ẹlomiran tabi kikorira idẹra ẹlomiran."
"Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: {Àti níbi aburú onílara nígbà tí ó bá ṣe ìlara 5} [Sūratul Falaq: 5]."
" Lati ọdọ Anas ọmọ Mālik - ki Ọlọhun yọnu si i - dajudaju Ojiṣẹ Ọlọhun - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - sọ pe:" "«Ẹ ma korira ara yin, ẹ ma ṣe keeta ara yin, ẹ ma kọyin si ara yin, ẹ jẹ - ẹyin ẹrusin Ọlọhun - ọmọ-ìyá» " "Al-Bukhāriy ati Muslim ni wọn gba a wa."