"Idahun- Níní ifẹ Ọlọhun- ti ọla Rẹ ga- "
Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: "{Àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo sì le jùlọ nínú ìfẹ́ sí}." "[Surah Al-Baqarah: 165]"
"Nini ifẹ ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a-. "
o so pe: “Mo fi Ẹni ti ẹmi mi n bẹ ni ọwọ Rẹ bura, ẹnikẹni ninu yin o ni tii di olugbagbọ titi maa fi di ẹni ti o ni ifẹ si ju obi rẹ ati ọmọ rẹ lọ”. "Al-Bukhāriy ni o gba a wa."
"Nini ifẹ awọn Mu'mini, ati nini ifẹ daadaa fun wọn gẹgẹ bi o ṣe nífẹ̀ẹ́ rẹ fun ara rẹ."
"Anabi - ki ikẹ ati ọla maa ba a - sọ pe:" "«Ẹnikẹni ninu yin o le tii pe ni igbagbọ titi ti yio fi maa fẹ fun ọmọ-ìyá rẹ nkan ti n fẹ fun ara rẹ»" "Al-Bukhāriy ni o gba a wa."