"Ibeere 24: Darukọ awọn ẹkọ sisin?"

"Idahun-1- Gbigbe ọwọ tabi aṣọ tabi aṣọ pelebe ìnujú si imu nígbà tí a ba sin."

"2- Ki o dupẹ fun Ọlọhun lẹyin sisin pe «AlhamduliLlāh»."

"3- Ki ọmọ-ìyá rẹ tabi ọrẹ rẹ o sọ fun un pe: «Yarhamuka Llāhu»."

"Ti o ba ti wa sọ bẹẹ fun un: ki o yaa sọ pe: «Yahdīkumu Llāhu wa yuslihu bālakum»."