"Idahun- lati ọdọ Anas -ki Ọlọhun yọnu si i-, Ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe: " “Ẹni kan kan ninu yin o ni tii di olugbagbọ titi yoo fi fẹ fun ọmọ iya rẹ nnkan to fẹ fun ara rẹ”. " "Bukhari ati Muslim ni wọn gba a wa. "
"Ninu awọn anfaani to wa ninu Hadiisi naa: "
"1- O jẹ dandan fun olugbagbọ lati fẹ fun awọn olugbagbọ ninu dáadáa gẹgẹ bi o ṣe fẹ fun ara rẹ. "
Ati pe iyẹn wa ninu pipe igbagbọ.
"Hadiisi kẹjọ: "