Ibeere 20: Igba wo ni Israa' ati Mi'raaj waye?

Idahun: O wa ni ọmọ ọdun àádọ́ta. Ọlọhun si ṣe awọn irun márùn-ún ni ọranyan le e lori.

Idahun: Israa': Lati Mọṣalaṣi abeewọ lọ si Mọṣalaṣi Aq'saa.

Mi'raaj: Oun waye lati Mọṣalaṣi Aq'saah titi lọ si Sid'ratil mun'taha.