"Idahun- O da wa fun ijọsin Rẹ ni Oun nikan ṣoṣo ti ko si orogun kankan fun Un. "
"Ko kii ṣe tori iranu ati ere. "
Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: "{Àti pé Èmi kò ṣẹ̀dá àlùjànnú àti ènìyàn bí kò ṣe pé kí wọ́n lè jọ́sìn fún Mi 56} "[Surah Adh-Dhâriyât: 56]"