"Idahun- AL’MAHRUUF: Oun ni pipaṣe lati ṣe gbogbo itẹle Ọlọhun- Alagbara ti O gbọnngbọn-, AL-MUNKAR: Oun ni kikọ kuro nibi gbogbo ṣiṣẹ Ọlọhun Alagbara ti O gbọnngbọn.
Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: "{Ẹ jẹ́ ìjọ t’ó lóore jùlọ, tí A gbé dìde fún àwọn ènìyàn; ẹ̀ ń pàṣẹ ohun rere, ẹ̀ ń kọ ohun burúkú, ẹ sì gbàgbọ́ nínú Allāhu } "[Surah Âl-`Imrân: 110]"