"Ibeere ogoji: Ki ni igbarale Ọlọhun -ti ọla Rẹ ga- "

"Ibeere ogoji: Ki ni igbarale Ọlọhun -ti ọla Rẹ ga- "

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: "{Àti pé ẹnikẹ́ni tí ó bá gbẹ́kẹ̀lé Allāhu, Ó máa tó o } "[Surah At-Talâq: 3]"

"{Hasbuhu} : tabi O maa to fun un. "