"Idahun- Kalmatut Taohīd ni "Laa ilaaha illallahu", itumọ ẹ ni pe: Ko si ẹni tí ijọsin ododo tọ si afi Allahu. "
Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: Nítorí náà, mọ̀ pé dájúdájú kò sí ọlọ́hun tí ìjọ́sìn tọ́ sí àfi Allāhu. "[Suuratu Muhammad: 19]"