"Ibeere ẹlẹẹkẹtadinlogoji: Ǹjẹ́ igbagbọ a maa lekun a si tun maa dínkù? "

"Idahun- igbagbọ maa n lekun pẹlu itẹle a si maa dínkù pẹlu ẹṣẹ. "

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: "{Àwọn onígbàgbọ́ òdodo ni àwọn t’ó jẹ́ pé nígbà tí wọ́n bá fi (ìyà) Allāhu ṣe ìrántí (fún wọn), ọkàn wọn yóò wárìrì, nígbà tí wọ́n bá sì ké àwọn āyah Rẹ̀ fún wọn, wọn yóò lékún ní ìgbàgbọ́ òdodo. Olúwa wọn sì ni wọ́n ń gbáralé 2} " "[Surah Al-Anfâl: 2]"