"Ibeere ẹlẹẹkarundinlogoji: Ta ni awọn ọrẹ ayo Ọlọhun -ti ọla Rẹ ga-? "

"Idahun- awọn ni onigbagbọ olubẹru. "

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: "{Gbọ́, dájúdájú àwọn ọ̀rẹ́ Allāhu, kò níí sí ìbẹ̀rù (ìyà ọ̀run) fún wọn, wọn kò sì níí banújẹ́ (lórí oore ayé) 62 (Àwọn ni) àwọn t’ó gbàgbọ́ lódodo, wọ́n sì máa ń bẹ̀rù (Allāhu) 63} " [Suuratu Yunus: 62, 63].