"Ibeere ẹlẹẹkẹrinlelọgbọn: Ki ni ojuṣe wa si awọn onimimọ musulumi? "

"Idahun- a maa nífẹ̀ẹ́ wọn, a maa ṣẹri pada si ọdọ wọn nipa awọn àlámọ̀rí ati awọn iṣẹlẹ ọtun ti sharia, ki a ma darukọ wọn afi pẹlu daada, ẹnikẹ́ni ti o ba darukọ wọn pẹlu nnkan miiran to yatọ si iyẹn ninu aburu; ko si ni oju-ọna. "

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: {Allāhu yóò ṣàgbéga àwọn ipò fún àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo àti àwọn tí A fún ní ìmọ̀ nínú yín. Allāhu sì ni Alámọ̀tán nípa ohun tí ẹ̀ ń ṣe níṣẹ́ 11} [Suuratul-Mujadila 11].