"Ibeere ẹlẹẹkẹta: Ta ni Anọbi rẹ? "

"Idahun- Anọbi Muhammad (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a). "

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: {Muhammad ni Òjíṣẹ́ Allāhu ...} "[Surah Al-Fath: 29]"