"Idahun- awọn ni awọn iyawo Anabi -ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a-. "
Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: "{Ànábì ní ẹ̀tọ́ sí àwọn onígbàgbọ́ òdodo ju ẹ̀mí ara wọn lọ (nípa ìfẹ́ rẹ̀ àti ìdájọ́ rẹ̀). Àwọn aya rẹ̀ sì ni ìyá wọn} [Suuratul-Ahzaab: 6].