"Idahun- Sàábé ni: Ẹni ti o ba pade Anabi -ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ti o gba a gbọ ti o si ku sori Isilaamu. "
"- A maa nífẹ̀ẹ́ wọn, a si maa kọ iṣe wọn, awọn ni ẹni ti o dara julọ ti wọn si lọla julọ ninu awọn eeyan lẹyin awọn Anabi. "
"Awọn ti wọn lọla julọ ninu wọn ni awọn arole mẹrẹẹrin: "
"Abu Bakr -ki Ọlọhun yọnu si i-."
"Umar -ki Ọlọhun yọnu si i-.
"Uthman -ki Ọlọhun yọnu si i-.
"Aliy- ki Ọlọhun yọnu si i-. "