Idahun- Ọlọhun o nii gba nkan ti o yatọ si Isilaamu.
Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: {Ẹnikẹ́ni tí ó bá wá ẹ̀sìn kan ṣe yàtọ̀ sí ’Islām, A ò níí gbà á lọ́wọ́ rẹ̀. Ní Ọjọ́ Ìkẹ́yìn, ó sì máa wà nínú àwọn ẹni òfò 85}. [Suuratu Al-Imran 85]"