"Idahun- Ẹsin mi ni Isilaamu, oun ni: Jijupa-jusẹ fun Ọlọhun pẹlu igbagbọ ninu Ẹ ni Oun nikan ṣoṣo, ati itẹriba fun Un pẹlu itẹle, ati mimọ kuro nibi ẹbọ ati awọn ẹlẹbọ. "
Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: Dájúdájú ẹ̀sìn t’ó wà lọ́dọ̀ Allāhu ni ’Islām. [Surah Âl-`Imrân: 19]"