"Ibeere ẹlẹẹkẹrindinlogun: Ki ni alaye (itumọ) Al-Qur'ān? "

"Idahun- Ọrọ Ọlọhun -ti ọla Rẹ ga- ni, kii ṣe nnkan ti a da. "

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: {Tí ẹnì kan nínú àwọn ọ̀sẹbọ bá wá ètò ààbò wá sọ́dọ̀ rẹ, ṣ’ètò ààbò fún un títí ó fi máa gbọ́ ọ̀rọ̀ Allāhu...} [Suuratu At-Tawbah: 6].