"Ibeere ẹlẹẹkẹtala: Ǹjẹ́ ẹnikankan yatọ si Ọlọhun -ti ọla Rẹ ga- ni imọ ikọkọ? "

"Idahun- ẹnikankan o ni imọ ikọkọ afi Ọlọhun nikan ṣoṣo. "

Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: "{Sọ pé: “Àwọn t’ó wà nínú àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀ kò nímọ̀ ìkọ̀kọ̀ àfi Allāhu. Àti pé wọn kò sì mọ àsìkò wo ni A máa gbé àwọn òkú dìde 65} " "[Suuratun Naml: 65]"