"Idahun- mimu orogun pẹlu Ọlọhun ti ọla Rẹ ga”
Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pe: "{Dájúdájú Allāhu kò níí foríjin (ẹni tí) ó bá ń ṣẹbọ sí I. Ó sì máa ṣàforíjìn fún ohun mìíràn yàtọ̀ sí ìyẹn fún ẹni tí Ó bá fẹ́. Ẹni tí ó bá ń ṣẹbọ sí Allāhu, dájúdájú ó ti dá àdápa irọ́ (tí ó jẹ́) ẹ̀ṣẹ̀ ńlá 48}" "[Surah An-Nisâ': 48]"